Àwọn ohun ìmúṣiṣẹ́ ti Ẹ̀rọ ìgbàlódé


Àwọn ohun ìmúṣiṣẹ́ ti Ẹ̀rọ ìgbàlódé ti fídíò

  1. Ìwífúnni ti fídíò
    Npèsè Ìwífúnni nípa fídíò tí a ńfi ṣeré.
  2. Ṣe àbápín
    Ńfún ọ láàyè láti ṣabápín fídíò náà nípa ṣíṣe ẹ̀dà ìsopọ̀ àti pípín in nípa ẹ̀rọ ayélujára tàbí IM. O lè ṣe àbápín bákannáà ní lílo Ojúìwé tàbí Twíítà
  3. Ìsopọ̀
    Ńfún ọ láàyè láti ṣe ẹ̀dà àti láti ṣe àbápín ìsopọ̀ wẹ́ẹ̀bù náà
  4. Wànínú
    Ńfún ọ láàyè láti ṣe ẹ̀dà ẹ̀nà tó wànínú ẹ̀rọ ìgbàlódé àti kí a fi ẹ̀rọ ìgbàlódé náà kún ibi wẹ́ẹ̀bù tàbí blọ́ọ́gù
  5. Bọ́tìnì ìmúṣiṣẹ́/Ídáwọ́dúró
  6. Atúkọ̀
    Atúkọ̀ náà fi àkókò ẹnà ti fídíò náà hàn ọ́ ó sì fún ọ ní ààyè láti lọ sí àwọn àmìn nínú fídíò náà nípa títì í síwájú àti sẹ́hìn.
  7. Bọ́tìnì DVR Ààyè
    Nígbàtí o bá ńwo ìṣàn fídíò ààyè kan o lè tìí sí àmìn titẹ́lẹ̀ kan nínú fídíò náà tàbí kí o fọwọ́kan bọ́tìnì ídáwọ́dúró náà, bọ́tìnì ti ààyè náà yíò mú àwọ rẹ́súrẹ́sú jáde. Títi bọ́tìnì àyè náà lẹ́ẹ̀kansi yíò mú kí fídíò ná fò padà sí ààyè àti pé bọ́tìnì náà yíò tún padà sí àwọ̀ ewé nígbàtí a bá ńwo fídíò ààyè náà. (Nígbàtí a bá ńwo fídíò lórí bíbèèrè fún, bọ́tìnì ààyè náà yíò wà láìlèṣiṣẹ́ ìwọ yíò sì lè tíì sí àmì èyíkéyìí nínú fídíò náà).
  8. Àwọn ọ̀rọ̀ ìsàlẹ̀ fídíò tí ó wà ní pípadé
    tẹ bọ́tìnì yí láti wòó pẹ̀lú Àwọn ọ̀rọ̀ ìsàlẹ̀ fídíò tí ó wà ní pípadé. Láti wo àwọn ọ̀rọ̀ ìsàlẹ̀ fídíò tí ó wà ní pípadé lórí ẹ̀rọ iOS tẹ̀lé àwọn àṣẹ wọ̀nyí:

    • Tẹ “Àwọn Àgbékalẹ̀”
    • Tẹ “Àwọn fídíò”
    • Yí “Àwọn ọ̀rọ̀ ìsàlẹ̀ fídíò tí ó wà ní pípadé” sí “Tàn án”
  9. Kíkún Ìbòjú
    Tẹ bọ́tìnì yí láti wo fídíò náà ní kíkún ìbòjú.

  10. òdíwọ̀n
    Tẹ bọ́tìnì yí láti darí òdiwọ̀n náà.