Fríẹ́ndì
Kíni Àdúrà jẹ́?
Oṣù Kẹrin 2024


Kíni Àdúrà jẹ́? Fríẹ́ndì, Oṣù Kẹ́rin, 2024, 46–47.

Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Frẹ́ndì , Oṣù Kẹ́rin, 2024

Kíni Àdúrà jẹ́?

Àwòrán
ọmọdébìnrin ngbàdúra ní ẹ̀gbẹ́ bùsùn

Àwọn ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Àdúrà ni bí a ṣe nsọ̀rọ̀ pẹ̀lú Baba Ọ̀run.

Àwòrán
Ọmọdékùnrin lórí pápá-ìṣeré

A lè gbàdúrà nígbàkugbà, níbikíbi. Baba Ọ̀run yíò gbọ́ wa nígbàgbogbo.

Àwòrán
Ọmọdékùnrin ngbàdúrà nínú Alakọbẹrẹ

À nlo àwọn ọ̀rọ̀ tí ó fi ìfẹ́ àti ọ̀wọ̀ hàn nígbàtí a bá ngbàdúrà.

Àwòrán
Ọmọdékùnrin ngbàdúrà pẹ̀lú ẹbí

A dúpẹ́ Baba Ọ̀run fún àwọn ìbùkún wa. A sì lè bèèrè lọ́wọ́ Rẹ̀ fún ìrànlọ́wọ́.

Àwòrán
Ọmọdébìnrin ngbàdúrà lórí ibùsùn

Mo lè ní ìmọ̀lára ifẹ́ ti Baba Ọ̀run ní ẹ̀ẹ̀kọ̀ọ̀kan tí mo bá gbàdúrà!

Kíkùn Ojú-ewé

Mo Lè Gbàdúrà sí Baba Ọ̀run

Àwòrán
yí ọ̀rọ̀ kíkọsílẹ̀ padà níhin

Ìjúwe láti ọwọ́ Adam Koford

Kíni ẹ ngbàdúrà nípa rẹ̀?