2013
Sísìn ní Gbogbo Àkókò
OṢù Owewe 2013


Àwọn Ọmọdé

Sísìn ní Gbogbo Àkókò

Olùdarí Utchdorf kọ́ni pé á níláti “sìn tìdùnnú tìdùnnú ati pẹ̀lú àìlọ́ra ni gbogbo ojú ọjọ ati ni gbogbo àkókò.” Kínni díẹ̀ nínú awọn ọ̀nà ti o fi le sìn awọn ẹlòmíràn ni ìgbà òtútù? Kínni díẹ̀ nínú awọn ọ̀nà ti o fi le sìn ni ìgbà rírú ewé? Báwo ni nípa ìgbà ooru ati òjò? Kọ awọn èrò ọkàn rẹ sílẹ̀ fun àkókò kọ̀ọ̀kan. O lè fẹ́ lati gbìyànjú lílo ọ̀kan ninu awọn èrò ọkàn rẹ ní oṣù yi!