2014
Ṣètò Ìkórè Rẹ
August 2014


Àwọn Ọmọdé

Ṣètò Ìkórè Rẹ

Òfin Ọlọ́run ti ìkórè ní pé tí a bá fẹ́ ohun kan lẹ́hìnnáà, a ní láti ṣiṣẹ́ fún un nísisìnyí. Tí a bá fẹ́ kí ọgbà kan hù, a nílò láti gbin àwọn èso, bomi rin wọ́n, kí a sì dáàbò bò wọ́n kúrò lọ́wọ́ àwọn koríko. Tí a kò bá ṣe èyí, a kò ní ní ìkórè kankan lẹ́hìnnáà!

Nísàlẹ̀ yí ni orúkọ àwọn “èso” rere kan tí ẹ lè nífẹ́ sí nínú ayé yín wà. Kọ àwọn ohun kan tí ẹ lè ṣe lóṣù yí láti ràn yín lọ́wọ́ láti gba àwọn ìbùkún wọ̀nyí.