2015
Olùgbàlà Yíò Tù Ọ́ Nínú
March 2015


Àwọn Ọmọdé

Olùgbàlà Yíò Tù Ọ́ Nínú

Bèèrè lọ́wọ́ mọlẹ́bí tàbí ọ̀rẹ́ kan nípa àsìkò kan nígbàtí ọkùnrin tàbí obìnrin náà ti ní ìmọ̀lọ́kàn ìtùnú láti ọ̀dọ̀ Olùgbàlà. Tiraka láti ronú nípa àsìkò kan nígbàtí Olùgbàlà tù ọ́ nínú. O lè ya àwòrán kan nípa ìrírí náà kí o sì fi kọ́ íbi ibùsùn rẹ láti rán ọ létí pé Jésù Krístì yíò fi ìgbàgbogbo wà níbẹ̀ láti tù ọ́ nínú.