2015
Igboyà nínú àwọn Ìwé Mímọ́
OṢù Ìgbé 2015


Àwọn Ọmọdé

Ìgboyà nínú àwọn Ìwé Mímọ́

Ààrẹ Monson kọ́ wa láti ní ìgboyà kí a sì dúró fún ohun tí a gbàgbọ́. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àpẹrẹ ni ó wà nínú àwọn ìwé mímọ́ nípa àwọn ènìyàn tí wọ́n fi ìgboyà hàn. Ka ìwé mímọ́ tí ó tẹ̀lé orúkọ kọ̀ọ̀kan. Báwo ni àwọn ènìyàn wọ̀nyí ṣe fi ìgboyà hàn àti dìde sókè fún ohun tí wọ́n mọ pé ó tọ́? O lè kọ tàbí ya àwòrán kan nípa àwọn ìfèsì rẹ.

Daniel (Daniel 6:7, 10–23)

Esther (Esther 4:5–14; 5:1–8; 7:1–6)

Samuel the Lamanite (Helaman 13:2–4; 16:1–7)

Joseph Smith (Joseph Smith—History 1:11–17)