2016
Kíkọ́ nípa Jésù
OṢù Ẹrẹ̀nà 2016


Àwọn Ọmọ

Kíkọ́ nípa Jésù

Ẹ̀mí Mímọ́ nfún wa ní àwọn ìmọ̀lára tí ó ní àláfíà láti rànwá lọ́wọ́ láti mọ̀ pé Jésù jẹ́ òtítọ́ àti pé ó nífẹ́ wa. Kọ sílẹ̀ tàbí ya àwòrán ohun kan tí ẹ̀yin yíò níláti kọ́ nípa Jésù.