2022
Mósè àti Mánà náà
Oṣù Kẹrin 2022


Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù “Mose àti Mánà náà” Fríẹ́ndì , Oṣù Kẹ́rin 2022

“Mósè àti Mánà náà”

Ọ̀rọ̀ Oṣooṣù Fríẹ́ndì Oṣù Kẹ́rin 2022

Mósè àti Mánà náà

Àwòrán
Mósè àti àwọn ọmọ Ísráẹ́lì

Àwọn Ìjúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Ábráhámù jẹ́ wòlíì kan. Ó darí àwọn ènìyàn Ọlọ́run lọ sí ilẹ̀ ìlérí. Wọ́n rìn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọjọ́.

Àwòrán
àwọn ọmọdé pẹ̀lú mánà

Ebi npa àwọn ènìyàn. Wọn kò ní oúnjẹ. Nítorínà Olọ́run rán oúnjẹ sí wọn láti ọ̀run. A pèé ni mánà.

Àwòrán
ìyá àti ọmọ nmúra mánà sílẹ̀

Nì òwòwúrọ̀, àwọn ènìyàn npéjọpọ̀ láti jẹ mánà. Ṣùgbọ́n kì í dúro ní titun di òru-mọ́jú. Wọn níláti kó púpọ̀ jọ si ní ọjọ́ kejì.

Àwòrán
Krístì pẹ̀lú àwọn ọmọdé

Mánà náà rán wa létí nípa Jesu Kristi. Ọlọ́run rán mánà láti gba àwọn ènìyàn rẹ̀ là. Bákannáà Ó rán Jésù wá sí ayé láti gbà wá là. A nílò Jesu lójojúmọ́, gẹ́gẹ́ bí a ṣe nílò oúnjẹ lójojúmọ́.

Àwòrán
Àwọn ọmọdé nwo àwòrán Jesu Kristi

Èmi yíò tẹ̀lé Jésù Òun yíò fún mi ní okun yíó sì rànmí lọ́wọ́ láti ní ìmọ̀lára ìfẹ Rẹ̀ lójojúmọ́.

Kíkùn Ojú-ewé

A Nílò Jésù Lójojúmọ́

Àwòrán
Krístì pẹ̀lú àwọn ọmọdé

Tẹ̀ àwòrán náà láti ṣe ìgbàsílẹ̀.

Apejúwe láti ọwọ́ Apryl Stott

Báwo ni Jesu ṣe ràn ọ́ lọ́wọ́?