2013
Jẹ́ Olùlànà kan
July 2013


Àwọn Ọmọdé

Jẹ́ Olùlànà kan

Ààrẹ Monson sọ wípé olùlànà ní ẹnití ó nfi ọ̀nà han fún àwọn ẹlòmíràn láti tẹ̀lé. Kíni ó lè ṣe láti dúró fún ohun tí ó tọ́ àti láti jẹ́ olùlànà fún àwọn ẹlòmíràn ní agbègbè rẹ àti ní ìdílé rẹ? Kọ àwọn ìdáhùn re sì ṣe alábápín wọn pẹ̀lú ìdílé rẹ.