2017
Ìṣura Òtítọ́
OṢù Èrèlè 2017


Àwọn Ọmọ

Ìṣura Òtítọ́

Ààrẹ Monson sọ ìtàn nípa ìyá kan tí ó ní àpótí ìṣura pàtàkì kan. Nígbàtí àwọn ọmọ rẹ̀ ṣí àpótí náà, wọ́n rí àwọn fọ́tò ara wọn. Ìṣura ìyá náà ni ẹbí rẹ̀!

Ìṣura tòótọ́ kìí ṣe wúrà tàbí àwọn ẹ̀gbà—ó jẹ́ àwọn ènìyàn tí ẹ fẹ́ràn. Tani ẹ fẹ́ràn? Ya àwórán àpótí ìṣura kan pẹ̀lú fọ́tò wọn tàbí orúkọ wọn nínú àpótí náà.