2017
Ẹ gbe ìhámọ́ra Yín Wọ̀
March 2017


Àwọn Ọmọdé

Ẹ gbe ìhámọ́ra Yín Wọ̀

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun búburú ni ó wà ní ayé òde òní. Ìhìnrere ni ó dàbí asà tí ó ndá ààbò bò wá. Ka ohun mẹwa tí Ààrẹ Eyring sọ fún wa láti ṣe láti dá ààbò bo ara wa. Nígbànáà ya àwòrán kí o sì kun àsà tìrẹ!

  1. Ya ọjọ́ ìsinmi sí mímọ́

  2. Bu ọlá fún oyèàlùfáà

  3. Dá kí o sì pa májẹ̀mú mọ́

  4. Ṣiṣẹ́ lórí ìwé ìtàn ẹbí

  5. Lọ sí tẹ́mpìlì

  6. Ronúpìwàdà

  7. Gbàdúrà

  8. Sin àwọn ẹlòmíràn

  9. Ṣe Àbápín Ẹ̀rí Rẹ

  10. Ka àwọn ìwé mímọ