Oṣù Kẹ́jọ 2022 Kíni Ìpàdé Ilé Ìrọ̀lẹ́ Jẹ́?Àkópọ̀ kan nípa ṣíṣe ìpàdé ilé ìrọ̀lẹ́ àwọn Ènìyàn Mímọ́ Ọjọ́-ìkẹhìn. Fún Okun àwọn Ọ̀dọ́ Fún Ọ̀dọ́: Fìtílà sí Ẹsẹ̀ WaFìtílà olóòróró ìrọ̀rùn kan láti ìgbà àtijọ́ lè kọ́ wa bí Olúwa ṣe ntọ́ wa sọ́nà. Fríẹ́ndì Fún àwọn Ọmọdé: Àwọn ìwé-orin Dáfídì Kọ́ni Nípa Jésù KrístìKà nípa àwọn Ìwé-orin Dáfídì nínú Májẹ̀mú Láéláé.