2018
Rírántí Jésù
February 2018


Àwọn Ọmọdé

Rírántí Jésù

Àwọn Ìwé mímọ́ kọ́ni pé a gbọ́dọ̀ rántí Jésù Krístì nígbàgbogbo. Èyí tùmọ̀ sí pé a gbọ́dọ̀ ronú nípa Rẹ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ kí a sì tẹ̀lé àpẹrẹ Rẹ̀!

Bí ẹ̀yin bá sì nrántí mi nígbàgbogbo ẹ̀yin yío ní Ẹ̀mí mi láti wà pẹ̀lú yín.

“Bí ẹ̀yin bá sì nrántí mi nígbàgbogbo ẹ̀yin yío ní Ẹ̀mí mi láti wà pẹ̀lú yín.” (3 Nephi 18:7).