Oṣù Kẹfà 2022 Kí Ló NṢẹlẹ̀ Nínú Àwọn Ìpàdé Ìjọ Ọjọ́ Ìsinmi?Àkópọ̀ ìpìlẹ̀ ti àwọn ìpàdé Ìjọ Ọjọ́ Ìsinmi. Fún Okun àwọn Ọ̀dọ́ Fún Ọ̀dọ́: YànWo àlàyé kan ti ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Jóṣhúà 24:15 . Fríẹ́ndì Fún Àwọn Ọmọdé: Rutu and NàómìKa ìtàn ti Rutu àti Nàómì láti inú Májẹ̀mú Láéláé.